Yorùbá Bibeli

A. Oni 21:18 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn awa kò lè fi aya fun wọn ninu awọn ọmọbinrin wa: nitoriti awọn ọmọ Israeli ti bura, wipe, Egún ni fun ẹniti o ba fi aya fun Benjamini.

A. Oni 21

A. Oni 21:12-24