Yorùbá Bibeli

A. Oni 2:3 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitorina emi pẹlu wipe, Emi ki yio lé wọn jade kuro niwaju nyin; ṣugbọn nwọn o jẹ́ ẹgún ni ìha nyin, ati awọn oriṣa wọn yio di ikẹkun fun nyin.

A. Oni 2

A. Oni 2:1-11