Yorùbá Bibeli

A. Oni 16:12 Yorùbá Bibeli (YCE)

Bẹ̃ni Delila mú okùn titun, o si fi dè e, o si wi fun u pe, Awọn Filistini dé, Samsoni. Awọn ti o lumọ́ dè e wà ninu yará. On si já wọn kuro li apa rẹ̀ bi owu.

A. Oni 16

A. Oni 16:2-22