Yorùbá Bibeli

A. Oni 14:9 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si bù ninu rẹ̀ si ọwọ́ rẹ̀, o si njẹ ẹ li ajẹrìn, titi o si fi dé ọdọ baba ati iya rẹ̀, o si fi fun wọn, nwọn si jẹ: ṣugbọn on kò sọ fun wọn pe ninu okú kiniun li on ti mú oyin na wá.

A. Oni 14

A. Oni 14:3-10