Yorùbá Bibeli

A. Oni 13:5 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitori kiyesi i, iwọ o lóyun, iwọ o si bi ọmọkunrin kan; ki abẹ ki o má ṣe kàn a lori: nitori Nasiri Ọlọrun li ọmọ na o jẹ́ lati inu wá: on o bẹ̀rẹsi gbà Israeli li ọwọ́ awọn Filistini.

A. Oni 13

A. Oni 13:1-9