Yorùbá Bibeli

A. Oni 13:1 Yorùbá Bibeli (YCE)

AWỌN ọmọ Israeli si tun ṣe eyiti iṣe buburu li oju OLUWA; OLUWA si fi wọn lé awọn Filistini li ọwọ́ li ogoji ọdún.

A. Oni 13

A. Oni 13:1-7