Yorùbá Bibeli

A. Oni 11:8 Yorùbá Bibeli (YCE)

Awọn àgba Gileadi si wi fun Jefta pe, Nitorina li awa ṣe pada tọ̀ ọ nisisiyi, ki iwọ ki o le bá wa lọ, ki o si bá awọn ọmọ Ammoni jà, ki o si jẹ́ olori wa ati ti gbogbo awọn ara Gileadi.

A. Oni 11

A. Oni 11:1-18