Yorùbá Bibeli

A. Oni 11:35 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si ṣe nigbati o ri i, o fà aṣọ rẹ̀ ya, o si wipe, Yẽ, ọmọ mi! iwọ rẹ̀ mi silẹ gidigidi, iwọ si li ọkan ninu awọn ti nyọ mi lẹnu: nitori emi ti yà ẹnu mi si OLUWA, emi kò si le pada.

A. Oni 11

A. Oni 11:27-37