Yorùbá Bibeli

A. Oni 11:29 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbana li ẹmi OLUWA bà lé Jefta, on si kọja Gileadi ati Manasse, o si kọja Mispa ti Gileadi, ati lati Mispa ti Gileadi o si kọja lọ sọdọ awọn ọmọ Ammoni.

A. Oni 11

A. Oni 11:21-38