Yorùbá Bibeli

A. Oni 1:21 Yorùbá Bibeli (YCE)

Awọn ọmọ Benjamini kò si lé awọn Jebusi ti ngbé Jerusalemu jade; ṣugbọn awọn Jebusi mbá awọn ọmọ Benjamini gbé ni Jerusalemu titi di oni.

A. Oni 1

A. Oni 1:19-31