Yorùbá Bibeli

A. Oni 1:16 Yorùbá Bibeli (YCE)

Awọn ọmọ Keni, ana Mose, si bá awọn ọmọ Juda gòke lati ilu ọpẹ lọ si aginjù Juda, ni gusù Aradi; nwọn si lọ, nwọn si mbá awọn enia na gbé.

A. Oni 1

A. Oni 1:6-26